Competition in this pair is now closed. Discussion and feedback about the competition in this language pair may now be provided by visiting the "Discussion & feedback" page for this pair. Entries may also be individually discussed by clicking the "Discuss" link next to any listed entry. Source text in English Who cast that first fateful tomato that started the La Tomatina revolution? The reality is no one knows. Maybe it was an anti-Franco rebellion, or a carnival that got out of hand. According to the most popular version of the story, during the 1945 festival of Los Gigantes (a giant paper mâché puppet parade), locals were looking to stage a brawl to get some attention. They happened upon a vegetable cart nearby and started hurling ripe tomatoes. Innocent onlookers got involved until the scene escalated into a massive melee of flying fruit. The instigators had to repay the tomato vendors, but that didn't stop the recurrence of more tomato fights—and the birth of a new tradition.
Fearful of an unruly escalation, authorities enacted, relaxed, and then reinstated a series of bans in the 1950s. In 1951, locals who defied the law were imprisoned until public outcry called for their release. The most famous effrontery to the tomato bans happened in 1957 when proponents held a mock tomato funeral complete with a coffin and procession. After 1957, the local government decided to roll with the punches, set a few rules in place, and embraced the wacky tradition.
Though the tomatoes take center stage, a week of festivities lead up to the final showdown. It's a celebration of Buñol's patron saints, the Virgin Mary and St. Louis Bertrand, with street parades, music, and fireworks in joyous Spanish fashion. To build up your strength for the impending brawl, an epic paella is served on the eve of the battle, showcasing an iconic Valencian dish of rice, seafood, saffron, and olive oil.
Today, this unfettered festival has some measure of order. Organizers have gone so far as to cultivate a special variety of unpalatable tomatoes just for the annual event. Festivities kick off around 10 a.m. when participants race to grab a ham fixed atop a greasy pole. Onlookers hose the scramblers with water while singing and dancing in the streets. When the church bell strikes noon, trucks packed with tomatoes roll into town, while chants of "To-ma-te, to-ma-te!" reach a crescendo.
Then, with the firing of a water cannon, the main event begins. That's the green light for crushing and launching tomatoes in all-out attacks against fellow participants. Long distance tomato lobbers, point-blank assassins, and medium range hook shots. Whatever your technique, by the time it's over, you will look (and feel) quite different. Nearly an hour later, tomato-soaked bombers are left to play in a sea of squishy street salsa with little left resembling a tomato to be found. A second cannon shot signals the end of the battle. | Winning entries could not be determined in this language pair.There were 6 entries submitted in this pair during the submission phase. Not enough votes were submitted by peers for a winning entry to be determined.
Competition in this pair is now closed. | Tani ó ju tòmátì àkọ́kọ́ náà tí ó mú kí rògbòdìyàn La Tomatina bẹ̀rẹ̀? Òtítọ́ ibẹ̀ ni pé kò sí ẹnití ó mọ̀. Bóyá ìṣọ̀tẹ̀ ìṣòdì Faranse ni, tàbí àjọ̀dún kan tí kò ṣe é ṣàkóso mọ́. Gẹ́gẹ́ bí àlàyé tí ó wọ́pọ̀ jùlọ nípa ìtàn náà, lásìkò ayẹyẹ Los Gigantes ní ọdún 1945 (ìwọ́de àwọn ère nlá tí a fi amọ̀ oní-pépà ṣe), àwọn ara ìlú nwá ọ̀nà láti dá ìjà sílẹ̀ kí àwọn ènìyàn lè ṣàkíyèsi wọn. Wọ́n rí ọmọlanke kan tí ó kó oríṣiríṣi ewébẹ̀ àti èso nítòsí wọn lójijì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ síí ní ju àwọn tòmátì tó ti pọ́n nínú rẹ̀ nù. Àwọn òwòran tí kò mọ ohun tí nlọ náà darapọ̀ mọ́ wọn, títí tí ibi ìṣẹ̀lẹ̀ náà fi di ibi ìdàrúdàpọ̀ àwọn èso tí nfò kiri. Àwọn ọ̀dádá náà ní láti san àsanpadà fún àwọn tó ni tòmátì náà, ṣùgbọ́n èyí kò dá wíwáyé àwọn ìjà tòmátì náà nígbà mìíràn dúró —àti ìbẹ̀rẹ̀ àṣà titun. Nítorí ìbẹ̀rù pé kí ìjà náà má di ti ìgboro, àwọn aláṣẹ ìlú gbé àwọn oríṣiríṣi òfin tó de àwọn ènìyàn mọ́lẹ̀ jáde ni àwọn ọdún 1950, wọ́n dẹ àwọn òfin náà nílẹ̀ díẹ̀, wọ́n sì tún mú wọn le síi. Ní ọdún 1951, àwọn ara ìlú tí ó tàpá sí òfin náà ni a tì mọ́lé títí di ìgbà tí ariwo àwọn ara ìlú bèèrè fún ìtúsílẹ̀ wọn. Àfojúdi tí ó lókìkí jùlọ sí awọn òfin tó de ni mọ́lẹ̀ nípa ọ̀rọ̀ tòmátì náà ni ó wáyé ọdún 1957 nígbàtí àwọn kan ṣe ìsìnkú yẹ̀yẹ́ fún tòmátì pẹ̀lú pósí àti àpéjọ àwọn ènìyàn. Lẹ́yìn ọdún 1957, ìjọba ìbílẹ̀ pinnu láti da ara wọn pọ̀ mọ́ ohun tí n ṣẹlẹ̀, gbé àwọn òfin melo kan jáde, kí wọ́n sì tẹ́wọ́gba àṣà apanilẹ́ẹ̀rín náà. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tòmátì náà ni ó wọ́pọ̀ jù, ayẹyẹ lọ fún odindin ọ̀sẹ̀ kan títí di ìgbà ìjàkadì ìkẹyìn. Ó jẹ́ àkókò ayẹyẹ àwọn baba ìsàlẹ̀ àwọn ẹni mímọ́ Buñol, Maria Wúndíá àti ti St. Louis Bertrand, pẹ̀lú ìwọ́de ojú pópó, orin àti àwọn ohun ìṣeré tí n tanná gẹ́gẹ́ bí àṣà ìdùnnú àwọn ara Sípéènì. Láti fi agbára kún ara ẹni ní ìmúrasílẹ̀ ìjàkadì tí mbọ̀ lọ́nà, a má a n se ìrẹsì pàtàkì kan pẹ̀lú adìẹ àti àwọn oúnjẹ tí à nrí láti inú omi bíi ẹja, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ, ní alẹ́ ọjọ́ tí ó ṣáájú ìjàkadì náà, èyí tí n ṣàfihàn oúnjẹ akọni àwọn ara Valencia pẹ̀lú ìrẹsì, àwọn oríṣiríṣi oúnjẹ tí a n rí láti inú omi, èròjà oúnjẹ tí a n pé ní saffron,àti òróró ólífì. Lónìí, ayẹyẹ aláìní ìhámọ́ yìí ti ní ìlànà ètò díẹ̀ síi. Àwọn olùṣètò ti tẹ̀síwájú dé ibi pé wọn a má a gbin oríṣi tòmátì tí kò dùn rárá kan fún ayẹyẹ ọlọ́dọọdún náà. Ayẹyẹ a má a bẹ̀rẹ̀ ní agogo mẹ́ẹ̀wá òwúrọ̀, nígbàtí àwọn olùkópa a má a súré lọ láti lọ gbá ẹran ẹlẹ́dẹ̀ tí a so mọ́ òkè òpó elépo lára kan mú. Àwọn òwòran a má a lo okún oníhò tí a fi nfa omi láti fi fún omi sí àwọn ajìfà náà lára bí wọ́n ti nkọrin, tí wọ́n sì njó ní ojú òpópó. Nígbàtí aago ilé ìjọ́sìn bá lu mejila ọ̀sán, àwọn ọkọ̀ akẹ́rù tí ó kún fún tòmátì yóò yí wọlé sínú ìlú, nígbàtí ariwo "To-ma-te, to-ma-te!" yóò wá gba gbogbo òde kan. Nígbà náà, nípasẹ̀ omi fífọ́n kiri láti inú ìgò, ìṣẹ̀lẹ̀ náà gan-an-gan yóò wá bẹ̀rẹ̀. Ààmì ìtẹ̀síwájú ni èyí fún fífọ́ sí wẹ́wẹ́ àti jíju tòmátì káàkiri nínú ìdojú ìjà kọ àwọn ẹlẹgbẹ́ olùkópa. Àwọn ènìyàn tí ó mọ tòmátì jù láti ọ̀nà jíjìn, àwọn ògbójú apànìyàn, àti àwọn tó mọ̀ ọ́ jù láti ìtòsí yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ ọ́ lókò. Oríṣi ọ̀nà yòówù tí ìwọ bá mọ̀ ọ́ lò, nígbàtí ohun gbogbo yóò bá fi parí, ìwọ kì yóò jẹ́ ara rẹ mọ́. Bíi wákàtí kan lẹ́yìn náà, a ó fi àwọn tó mọ tòmátì jù bíi àdó olóró sẹ́yìn láti má a gbé ẹsẹ̀ ijó lọ́kọ̀ọ̀kan láàárín ọbẹ̀ tí kò sí ohun tí ó fi jọ ọbẹ̀ tòmátì mọ́. Omi fífọ́n káàkiri ẹlẹ́ẹ̀kejì ni ó jẹ́ ààmì òpin ìjàkadì náà. | Entry #21884 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
20 | 3 x4 | 3 x2 | 2 x1 |
- 1 user entered 5 "dislike" tags
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
- 1 user disagreed with "dislikes" (3 total disagrees)
-1 1 La Tomatina | Mistranslations "La Tomatina" can still be translated into Yoruba. "La" is an article in Spanish language meaning "The" in English and "Naa" in Yoruba language, and "Tomatina" can be translated as "Tomati" or Tomato" in Yoruba Language. | eltee | |
+1 1 wáyé ọdún | Omission Omssion of preposition "ni" between "waye" and "odun" | eltee | |
-1 1 Lẹ́yìn ọdún 1957, ìjọba ìbílẹ̀ pinnu láti da ara wọn pọ̀ mọ́ ohun tí n ṣẹlẹ̀, gbé àwọn òfin melo kan jáde | Omission There is omission of 3rd person phrasal pronoun "won si" in between "sele," and "gbe", so the statement should read "Leyin odun 1957, ìjọba ìbílẹ̀ pinnu láti da ara wọn pọ̀ mọ́ ohun tí n ṣẹlẹ̀, won si gbé àwọn òfin melo kan jáde" | eltee | |
kí | Grammar errors The use of modal verb "Ki" here is irrelevant and incorrect. The right word here should be "bakannaa" or "ni afikun" | eltee No agrees/disagrees | |
-1 1 nípasẹ̀ omi fífọ́n kiri láti inú ìgò | Mistranslations Th word "cannon" is not translated as "igo" but as "ibon nla" | eltee | |
| Tani o kọkọ ju tomati akọkọ naa ti da iṣọtẹ La Tomatina silẹ? Otitọ ibẹ ni wipe ko si ẹni ti o mọ. Boya iṣọtẹ alodi si ijọba Faranse tabi ayẹyẹ idaraya ti o kọja ààlà ni. Gẹge bii ẹya itan ti o wọpọ julọ, ni igba ayẹyẹ ti Los Gigantisi (tito awọn ère nla ti a fi pépà ṣe kọja) ti ọdun 1945, awọn ara adugbo nfẹ ṣeto ija kan lati pe awọn eniyan sọdọ wọn. Ni wọn ba kan ọmọlanke ewebẹ kan ni arọwọto ti wọn si bẹrẹ si ni sọ awọn tomati ti o ti pọn. Awọn oluworan ti ko mọ nkankan ba da sii titi ti iran naa fi di ija-igboro nla ti eso to nfo. Awọn ti o fàá ni lati san owó fun awọn ti o nta tomati naa, ṣugbọn eyi ko da wiwaye awọn ija tomati duro—ati ìbí aṣa atọwodọ titun kan. Awọn alaṣẹ, ni ibẹru iwa ti wọn ko ni le kapa, ṣe ofin, wọn tun rẹ ọwọ ofin naa silẹ, nigba ti o ya wọn tun mupada sipo awọn ofin ti o dèé lẹsẹsẹ ni awọn ọdun 1950. Ni ọdun 1951, awọn ara adugbo ti o tapa si ofin ni wọn timọle titi ti igbe awọn ara ilu fi pè fun itusilẹ wọn. Itapa si fifi ofin de tomati ti o lokiki julọ ṣẹlẹ ni ọdun 1957 nigbati awọn olufilọlẹ ṣe isinku ẹgan tomati kan pẹlu posi ati iwọde. Lẹyin ọdun 1957, ijọba ibilẹ pinnu lati ba igba mu, wọn fi awọn ofin kan lelẹ, ti wọn si faramọ aṣa atọwọdọwọ adẹrin pani naa. Bi o tilẹ jẹ wipe tomati ni o gbajumọ julọ, awọn ayẹyẹ ọlọsẹ kan maa nwaye ṣaaju asekagba yi. O jẹ ajọyọ ti awọn eniyan mimọ alatilẹyin Buñol, Wundia Maria ati St Louis Bertrand, pẹlu iwọde ni opopona, orin, ati fifi ina-mèremère dara pẹlu ayọ ni aṣa Spaniṣi. Lati mu agbara rẹ le fun ija igboro to nbọ, ounjẹ atijọ ti spaniṣi ni wọn maa njẹ ni alẹ ti o ṣaaju ija naa, eyiti o nfi irẹsi ti o gbajumọ ti Falenṣia, ohun jijẹ lati inu okun, ìtànná safurọnu, ati ororo olifi han. Loni, ayẹyẹ alaini idiwọ yii ti ni awọn odiwọn ètò. Awọn oluṣeto ti tẹsiwaju de bii wipe wọn gbin iru awọn tomati kan ti ko ṣe e jẹ fun iṣẹlẹ ọdọọdun naa. Ajọdun maa nbẹre ni bi aago mẹwa owurọ (10 a.m) nigbati awọn olukopa ba sare lati lọ gba ẹran ẹlẹda ti a ti yan ti o wa loke opo ti ti fi girisi yi mu. Awọn oluworan yoo maa tu omi si awọn ti o nwọ kiri naa lara ni bi wọn ṣe nkọrin ti wọn si njo ni awọn opopona. Ni igbati ti aago ṣọọṣi ba dun ni ọsan gan-gan, awọn ọkọ ti a ti di tomati si yoo wọlu, nigbati ariwo "Tomati, tomato!" yoo ta. Nigbanaa, pẹlu yinyin ibọn olomi, iṣẹlẹ gan-gan yoo bẹrẹ. Eyi ni imọlẹ atọka fun rírún ati jíju awọn tomati ni gbogbo ọna lati dojukọ awọn olukopa miiran. Awọn ti o le ju tomati lọ jinna rere, awọn asun mọni pani, ati awọn jiju ti ko jinna ju. Eyikeyi ti o jẹ ọna tirẹ, ni igba ti o ba pari, iwọ yoo da (ti iwọ yoo si ni imọlara) yatọ. Ni bii wakati lẹyin naa, awọn alado adugbamu ti tomati ti rin ni a o fi silẹ lati ṣere ninu okun opopona pẹlu tomati diẹ to sẹku lati wá rí. Ibọn yinyin elẹẹkeji yoo fi aami opin ija naa han. | Entry #19372 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
17 | 3 x4 | 2 x2 | 1 x1 |
- 2 users entered 6 "dislike" tags
- 2 users agreed with "dislikes" (3 total agrees)
| Omission there is omission of a word "o" between "ti" and "da". It should be written as "ti o da". | eltee | |
+1 Gẹge bii ẹya itan ti o wọpọ julọ, ni igba ayẹyẹ ti Los Gigantisi (tito awọn ère nla ti a fi pépà ṣe kọja) ti ọdun 1945, awọn ara adugbo nfẹ ṣeto ija kan lati pe awọn eniyan sọdọ wọn | Other There are no accents on the whole of the text. | eltee | |
mupada sipo awọn ofin ti o dèé lẹsẹsẹ | Spelling The word order here is incorrect. It should read "wọn tún mú àwọn òfin náà padà sípò" | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
ti ti fi girisi yi | Mistranslations This is not making any meaning. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
Ni bii wakati lẹyin naa | Omission It should read Ni bii wakati kan leyin naa. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Tani o jù tomato málegbàgbé àkọ́kọ́ yẹn tó bẹ̀rẹ̀ rògbòdìyàn La Tomatina náà. Òtítọ́ ibẹ̀ ni pé kò sí ẹni tí o mọ̀. Bóyá ìṣọ̀tẹ̀ ìlòdìsí-Franko kan ni, tabi ayẹyẹ-ojú-pópó kan tí ó bọ́wọ́ sórí ni. Gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà-ìtàn náà kan tó wọ́pọ̀ julọ, ní àkókò àjọ̀dún Los Gigantes ti ọdun 1945 (tí ó máa n wáyé nípa ríru òmìrán ọmọ-lá-n-gidi kan tí a fi ẹrọ̀fọ̀ bébà ṣe káàkiri), tí àwọn ọmọ onílẹ̀ kan n wọ́nà lati ṣe jàgìdíjàgan kan kí aráyé lè ba à tẹ́tí sí ẹ̀hónú wọn. N ṣe ni wọn ṣèèṣì ṣe alábàápàdé ọmọlanke ẹlẹ́fọ̀ọ́ kan nítòsi, tí wọn sì bẹ̀ẹ̀rẹ̀ sí ní sọ tomato pípọ́n lu ara wọn. Awọn tí n wòran jẹ́jẹ́ pẹ̀lú nkò mọ̀ igbà tí wọn darapọ̀ mọ́ wọn títí tí gbogbo rẹ̀ fi di iṣu-ata-yán-an-yan-an nla tí èṣo tí n fò fìrì kiri nínú afẹ́fẹ́. Àwọn adárúgúdù sílẹ̀ ọjọ́ náà ní lati sanwo fún àwọn onítomati ọ̀hùn, sùgbọ́n èyí kò kúkú dẹ́kun pé kí ìjà onítòmátì ma tún ṣe aláì-wáyé mọ́ – èyí ni bí ìṣẹ̀dálẹ̀ tuntun kan tún ṣe dáyé. Pẹ́lù ìbẹ̀rùbojo pé fìtínà lè wáyé, ni ìjọ̀ba ba ṣòfin, láti dín jàgídí-jàgan àjọ̀dún yìí kù, ni wọn bá ṣàgbékalẹ̀ onírúurú òfin láàrin ọdún 1950 láti gbẹ́sẹ̀ lé àjọ̀dún yìí. Ní ọdún 1951, àwọn ọmọ-onílẹ̀ ti wọn rúfin yìí ni wọn jù sí àtìmọ́lé títí dì ìgbà tí gbogbo ìlú pariwo lé ìjọba lórí láti dá wọn sílẹ̀. Ìtàpá sí òfin gbígbẹ́sẹ̀ lé àjọ̀dún tomati tí ó gbajúgbajà jùlọ wáyé ní ọdún 1957 nígbà tí àwọn tí wọn faramọ́ àjọ̀dún yìí ṣe ìsìnkú aláwádà kan fún tomati pẹ̀lú pósí àti ìwọ́de. Lẹ́yìn ọdún 1957, ni ìjọba ìbílẹ̀ bá gbà lati pẹ̀lú ọbọ jẹko wọn, wọn gbé àwọṅ ìlànà kan kalẹ̀, wọn sì fọwọ́sí ìṣẹ̀dálẹ̀ jákujàku náà. Bí o tilẹ̀ jẹ́ pé tomato ni ó ni àjọ̀dún yìí, àṣeyẹ ọlọ́ṣẹ̀ kan yóò ṣaájú àṣekágbá àjọ̀dún náà. Bí í ṣíṣe àyájọ àwọn ẹni mímọ́ ìlú Buñol, ti Maria Wundia àti ti Ẹni-Mímọ́ Louis Bertrand, pẹ̀lú àwọn ìwọ́de ojú-pópó, torin-tìlù, àti yínyin bísìkò ní bí àwọn ara ilẹ́ Spain ti máa n ṣe. Láti gba agbára silẹ de gídígbò tí n bọ̀ lọ́nà, wọn yóò bu oúnjẹ paella bà-n-tà-bàn-tà fun olúkúlukú ní àìsùn ọjọ́ ìjàdù náà, èyí tí í ṣẹ àwọn ounjẹ àdáyébá bí ìrẹsì, ẹran-òun-ẹja-odò, ìyẹ̀fun safuroni àti òróró ólífì. Lọ́jọ òní, àjọ̀dún kò-lókùn-lọ́rùn yìí ti ni ìjánu díẹ̀díẹ̀ báyíì. Àwọn aláàtò-àjọ̀dún ti ṣe é débi pé kí wọn lọ wá onírúurú àwọn ẹ̀sà tomati ní tìtorí àyẹyẹ ọlọ́dọọdún náà. Àjọ̀dún máa n bẹ̀rẹ̀ ní aago mẹ́wàá àárọ̀ nígbàtí àwọn olùkópa yóò sáré láti re ekìrí ẹran kan tí a so mọ́ orí òpó kan tí n yọ̀ bọ̀lọ̀bọ̀lọ̀. Tí àwọn ònwòran yóò sì máa fọ́n omi lu àwọn olùdíje yìí bí wọn ti n kọrin tí wọn sì n jó kiri ojú-pópó. Nígbà tí aago sọ́ọ́sì bá lù méjìlá ọ̀sán, àwọn ọkọ̀-akẹ́rù tí wọn kún dẹ́nu yóò bẹ̀rẹ̀ sí ní wọ̀lú, tí ariwo “To-ma-ti. To-ma-ti yóò sí gba gbogbo afẹ́fẹ́ kíkankíkan. Lẹ́yìn náà, ni wọn máa rọ́ àgbá olómi, tí gudugbẹ̀-ètò yóò sì bẹ̀rẹ̀. Èyí ni àmí eré-yá fún títẹ̀ àti sísọ okò tomato ní gbogbo ọ̀nà yóòwù sí ẹni ti olúkúlùkù ba dojú kọ. Ọta tomato atamátàṣè ọlọ́nà-jíṅjìn, ọta pẹ̀kí-n-pẹ̀kí, àti ọta kòjìn-kò-súnmọ́. Ọ̀nàkọnà yòówù tí o ba yàn, nígbà tí àsìkò bá fi máa tó, bí ìwọ yóò ṣe máa wò (àti bí ara rẹ ṣe máa rí) máa yàtọ̀. Lẹ́yìn bí ọgbọ̀n ìṣẹ́jú, wọn yóò fi àwọn sọ̀kò-sọ̀kò tí gbogbo ara wọn ti rin fún tomati sílẹ̀ kí wọn máa lúwẹ̀ẹ́ nínú pọtọpọ́tọ́ tí kòtilẹ̀ fi ibi kankan jọ tomato mọ́. Àgbá ẹlẹẹ̀kejì tí wọn bá rọ́ jásí pé àkókò gídígbò-gídìgbò ti parí ni yẹn. | Entry #21139 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
17 | 3 x4 | 2 x2 | 1 x1 |
- 2 users entered 7 "dislike" tags
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
bọ́wọ́ sórí ni | Spelling Except one refers back to the source text, one finds it difficult understanding what is being said. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
kò mọ̀ | Syntax nkò mọ̀ is i don't know. It should be kò mọ̀ | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
Pẹ́lù ìbẹ̀rùbojo pé fìtínà lè wáyé, ni ìjọ̀ba ba ṣòfin, láti dín jàgídí-jàgan àjọ̀dún yìí kù, ni wọn bá ṣàgbékalẹ̀ onírúurú òfin láàrin | Spelling This does not translate in full the English text. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
bísìkò | Spelling This does not translate fireworks as it is a trade name. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
ní tìtorí | Mistranslations This should be "nítorí". "ní tìtorí" is slang. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
tomato | Inconsistencies Tomato or tomati? which is the right translation for tomato in Yoruba? I guess it is Tomati. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Tani ó kọ́kọ́ ju tòmátì náà èyí tí ó bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìṣọ̀tẹ̀ ti La Tomatina? Òtítọ́ rẹ nipé kòsí ẹni tí ó mọ̀. Bóyá ìṣọ̀tẹ̀ aṣòdìsí Franko ni, tàbí àjọyọ̀ ìwọ́de ijó àti ilù tí ó ṣèṣì bọ́ sódì. Lára èyí tí ó wọ́pọ̀ nínu ìtàn náà, lákókò ajọ̀dún 1945 ti Los Gigante ( ìṣafihàn òmìrán àfi pépà ṣe), àwọn ìbílẹ̀ ń fa asọ̀ láti lè jẹ́kí wọ́n fiyèsí wọn. Wọ́n gúnlè kèké tí ńkó ewébẹ̀ ní ìtòsí tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ síní ju tòmátì pípọ́n. Àwọn olùwòran kópa nínu rẹ̀ tí ìwà yíi fi gbìnàyá sí jíju ohun èso ńlá. Àwọn tí ó ṣokunfà èyí nílò láti san owó ìdápadà fún olùta tòmátì, ṣùgbọ́n èyí kò dáwọ́ ìjù padà àwọn ìjà tòmátì dúró—àti ìṣẹ̀dá àṣà titun. Nítorí ìbẹrù ìrusókè tí akòle ṣàkóso, àwọn aláṣẹ pá láṣẹ, dẹwọ́, wọ́n sì tún ṣàfílélẹ̀ oríṣi ìfilọ̀ ìtagbangba ní àwọn ọdún 1950. Ni 1951, àwọn ìbílẹ̀ tí ó tàpá sófin yìí ní a tì mọ́lé títí tí àwọn ará ìlu kígbe síta fún ìdásílẹ̀ wọn. Ìṣáfojúdi tí ó lókìkí jùlọ sí ìfilọ̀ ìtagbangba ṣẹlẹ̀ ní 1957 nígbà tí àwọn olúdásílẹ̀ ṣe ìṣẹfẹ̀ ìtòkú tòmátì pẹ̀lú odindi pósí àti ìwọ́de ọ̀pọ̀ ènìyàn. Lẹ́hìn 1957, ìjọba ìbílẹ̀ dẹwọ́, wọ́n ṣe òfin titun, wọ́n sì faramọ́ àṣà aṣiwerè yíì. Bí-ó-tilẹ̀-jẹ́ wí pé tòmátì gba òde kan, ọ̀sẹ̀ kan ajòdún ṣòkunfà ọjọ́ ìkẹhìn ìfigagbága. Ó jẹ́ àjọyọ̀ ẹni mímọ́ aláàbò Buñol, Màríà Wúndíá àti Ẹni mímọ́ Louis Bertrand, pẹ̀lú ìwọ́de òpónà, orin, àti ayẹyẹ oríṣi iná jíjó ní ìlanà àjọyọ̀ àṣà ará Sípáìn. Láti ṣè’gbáradì okun rẹ fún asọ̀ tí ń bọ̀, a ńṣe ìpesè oúnjẹ àrà ọ̀tọ̀ onírẹsì ní alẹ́ ṣáájú ọjọ́ ogun, èyí tí ń ṣàfihàn ìrí Àkójọpọ̀ àwopọ̀kọ́ ìrẹsì, oúnjẹ odò, òdòdó àrà ọ̀tọ̀, àti òróró ólífì. Lónì, àjọ̀dún àìnídinwọ̀n yíi ní gbèndéke ètò. Àwọn olùgbékalẹ̀ ti rìn jìnnà ní gbíngbin àwọn àrà ọ̀tọ̀ tòmátì tí kò dùn lẹ́nu fún ètò ọdọdún yìí nìkan. Àjọ̀dún bẹ̀rẹ̀ ní bii agogo mẹ́wà òwúrọ̀, nígbà tí àwọn olùkópa sáré láti mú ẹran tí a somọ́ orí òpó yíyọ̀. Àwọn olùwóran tú omi sí ara àwọn olùjìjàdù nígbà tí wọ́n ń kọrin pẹ̀lú ijó ní òpópó. Nígbà tí ago ilé ìjọsìn lù lọ́sàn, àwọn ọkọ̀ tí ó kó tòmátì wọ̀’lú, nígbà tí ariwo "Tò-má-tì, tò-má-tì" dé góńgó. Nígbà náà, pẹ̀lú ìfomi s’ọ̀kò, ayẹyẹ gan an bẹ̀rẹ̀. Èyí ni ààmì fún ìfúnpa àti jíju tòmátì lòdì sí olùkópa mííràn. Olùjù tòmátì lọ́nà jínjín réré, apànìa ojúkojú, àti jíju àìjìnà. Èyíkéyì ọ̀nà ìṣàmúlò rẹ, nígbà tí àkókò yóò parí, wá (nímọ̀lárà) ti yatọ̀. Léhìn bii wákàtí kan, àwọn olùju àdó olóró tí ó rin pẹ̀lú tòmátì laófi sílẹ̀ láti ṣeré nínu òpópó èrojà tòmátì tí ó rọ̀ dẹ̀mùdẹ̀mù pẹ̀lú ohun kéréje tí ó jọ tòmátì tí a lèrí. Àgbá ìkejì tí a yìn ṣàfihàn òpin ogun. | Entry #18826 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
5 | 0 | 1 x2 | 3 x1 |
- 2 users entered 8 "dislike" tags
ipé | Grammar errors These are separate words. It should read "ni pé kò sí" | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
kèké | Spelling This word is not properly spelt; it is kẹ̀kẹ́ | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
owó ìdápadà | Spelling Word used does not fully portray the meaning in English. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
Nítorí ìbẹrù ìrusókè tí akòle ṣàkóso, àwọn aláṣẹ pá láṣẹ, dẹwọ́, wọ́n sì tún ṣàfílélẹ̀ oríṣi ìfilọ̀ ìtagbangba ní àwọn ọdún 1950. | Spelling Something is wrong with the word order that makes its meaning somehow. | Abiodun Adeleye No agrees/disagrees | |
ajòdún | Spelling Wrong spelling. It's àjọ̀dùn. | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
Láti ṣè’gbáradì | Syntax It's Láti gbáradì fún... | Olayemi Olabenjo No agrees/disagrees | |
| Tani Simẹnti ti akọkọ fateful tomati ti bere si ni La Tomatina Iyika? Awon otito, ko si ọkan o mo. Boya o je ohun egboogi-Franko iṣọtẹ, tabi kan Carnival ti o ni jade ninu ọwọ. Ni ibamu si awọn julọ gbajumo ti ikede awọn itan, nigba ti 1945 Festival Los Gigantes (kan omiran iwe mâché puppet Itolẹsẹ ọmọ ogun), awọn agbegbe won nwa lati ipele kan brawl lati gba diẹ ninu awọn akiyesi. Nwọn sele lori kan Ewebe fun rira nitosi ati ki o bere si hurling pọn awọn tomati. L'onlookers ni kopa ti titi ti nmu escalated sinu kan lowo melee ti flying eso. Awọn instigators ní lati san awọn tomati olùtajà, sugbon ti ko da awọn ifasẹyin diẹ tomati njà-ati awọn ibi ti titun kan atọwọdọwọ. Níbẹrù ohun unruly escalation, alase ti fi lelẹ, ihuwasi, ati ki o reinstated kan lẹsẹsẹ bans ni 1950s. Ni 1951, awọn agbegbe ti o defied ofin won ewon titi àkọsílẹ outcry ti a npe ni fun won sílẹ. Julọ olokiki effrontery si awọn tomati bans sele ni 1957 nigbati o waye proponents kan Mock tomati isinku ni pipe pẹlu kan ati ki o coffin procession. Lẹhin 1957, agbegbe ijoba pinnu lati fi eerun pẹlu awọn punches, ṣeto awọn ofin kan diẹ ninu ibi, ki o si gba esin naa wacky atọwọdọwọ. Tilẹ awọn tomati ya ile-ipele, ose kan ti festivities yorisi soke si ik showdown. O kan ajoyo ti Buñol ká patron mimo, awọn Virgin Màríà ati St Louis Bertrand, pẹlu ita parades, orin, ati ise ina ni joyous Spani njagun. Lati kọ soke rẹ agbara fun awọn impending brawl, ohun apọju paella ti wa ni yoo wa lori Efa ti ogun, showcasing ohun ala Valencian satelaiti ti iresi, onje bi eja, saffron, ati olifi epo. Loni, yi unfettered Festival ni o ni diẹ ninu awọn odiwon fun ibere. Awọn oluṣeto ti ki jina bi lati cultivate kan pataki orisirisi ti unpalatable tomati o kan fun awọn iṣẹlẹ lododun. Festivities tapa si pipa ni ayika 10 am nigbati awọn alabaṣepọ ije lati ja gba kan ti o wa titi ngbe atop kan greasy polu. Onlookers okun awọn scramblers pẹlu omi nigba ti orin ati jijo ni ita. Nigbati ijo Belii dasofo kẹfa, oko nla aba ti pẹlu awọn tomati eerun sinu ilu, nigbati chants ti "Lati-Ma-te, si-Ma-te!" de ọdọ kan crescendo. Nigbana, pẹlu awọn tita ibọn ti kan omi Kanonu, awọn iṣẹlẹ nla bere. Ti o ni ina alawọ ewe fun crushing ati gbesita ni gbogbo awọn tomati-jade ku lodi si elegbe awọn alabaṣepọ. Gun ijinna tomati lobbers, ojuami-òfo assassins, ati alabọde ibiti o kio Asokagba. Ohunkohun ti ilana rẹ, nipasẹ awọn akoko ti o ni lori, o yoo wo (ki o si lero) ohun ti o yatọ. O fere wakati kan nigbamii, tomati-soaked bombers ti wa ni sosi lati mu ninu omi kan ti squishy ita Salsa pẹlu kekere osi resembling kan tomati lati le ri. A keji Kanonu shot awọn ifihan agbara opin ogun. | Entry #21673 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
5 | 1 x4 | 0 | 1 x1 |
- 1 user entered 1 "dislike" tag
- 3 users agreed with "dislikes" (3 total agrees)
+3 3 Tani Simẹnti ti akọkọ fateful tomati ti bere si ni La Tomatina Iyika? Awon otito, ko si ọkan o mo. Boya o je ohun egboogi-Franko iṣọtẹ, tabi kan Carnival ti o ni jade ninu ọwọ. | Mistranslations Everything about this whole translation is wrong | Oludamilola I. Oyetoyan | |
| Taani çni tí ó ju tòmátì àkökö èyí tí ó bêrê àsà tòmátì jíjù mö ara çni? Òtítö ibê ni wí pe kò sí çni tí ó leè sô. Bóyá ó leè jë ìdìtê tako êyà faransé tàbí ayçyç kan tí apá ò ká mö ni. Gëgë bí ìtàn kan tí ó gbajú gbajà tí a gbö se wí, ní àkókò ôdún Losi Gìgántçsì ní ôdún 1945 (ní ibi tí wön tí máa ngbé òmìrán dômí tí wön fi tákàdá tí wön gún põ se yí ká ìlú), àwôn ômô ìbílê nwá õnà bí wön se leè pàtç rògbòdìyàn láàrin ìgboro kí wön leè fi polongo ara wôn. Lójijì ni wön bö sí orí ômôlanke kan tí ó wà ní ìtòsí, wön sì bêrê sí ní ju tòmátì tí ó ti pön mö ara wôn. Àwôn olùwòran tí wôn ò môwö-mçsê náà fi ara gbá ní bê títí tí õrõ náà fi di bí oò lô yà fún mi, tí gbogbo èèyàn sìí nsáré sókè-sódò nígbàtí èso tòmátì nfò kiri síhïn-sóhün. Àwôn tí wön bêrê õràn yí ní láti san owó fún onítòmátì náà, sùgbön èyí kò dá a dúró pé kí ìsêlê ìjà tòmátì ó má tún sçlê mö- bëêni kò se ìdádúró fún bíbí àsà tuntun. Ní ìbêrù pé kí àsà yìí má baà peléke sí i, àwôn alásç se òfin lákºkò kan, wön tún dç ôwö díê lára òfin náà, lëhìn náà wön tún se onírúurú òfin láti gbësê lé irú àsàkásá bëê, ìyçn ní ààrin ôdún 1950 sí 1959. Ní ôdún 1951, àwôn ômô ìbílê tí wön rú òfin yì í ni wön fi êwõn jura títí di ìgbà tí àwôn ará ìlu se ìwóde ìfêhónúhàn láti pè fún ìtúsílê wôn. Ìgbésê akin tí ó gbajú gbajà jùlô láti gbësê lé àsà tòmátì jíjù mö ara çni ni èyí tí ó wáyé ní ôdún 1957 nígbàtí àwôn tí ó se agbáteru òfin náà se ètò ìsìnkú çlëyà fún tòmátì pêlú pósí kan, tí wön sì tò löwõõwö. Lëhìn ôdún 1957, ìjôba ìbílê pinnu láti wá gbogbo õnà láti wá ojútü sí ìsòro yìí, wön gbé òfin bíi mélòó kan kalê, wá fi ôgbön fi ara mö àsà ríndinríndin yìí. Bíótilêjêwìpè tòmátì ni wön fi orí àjõdún yìí sô, onírúurú ètò ayõ-ôdún tí ó gba õsê kan gbáko wön ni won npiyamô títí di ôjö àsèkágbá jàgídíjàgan náà. Èyí jë ayçyç àyësí fún pátríónì mímö ti Bùnólì, Maria mímö àti Lúwìsì Bátírándì mímö, pêlú ìyankálü, orin, àti títan iná alárànbarà lönà tí ó bá àsà Sípánìshì mu. Láti gbaradì fún rògbòdìyàn tí ó seése kí ó sçlê, oúnjç ìsênbáyé tí wôn þpé ni pàëlà, órisìí oúnjç kan tí ó wöpõ ní agbègbè Fàlënsìà tí wôn fi ìrçsì, çran, çja àti ewébê pèse rê, ni wôn nhá fún àwôn akópa láti jç ní ôjö tí ayçyç onírògbòdìyàn yìí bá ku õla. Lónìí, ôdún yï tí kò ti ní ijànu tëlê rí ti wà létòlétò báyìí. Àwôn tí nse ètò ayçyç yìí ti wá sé débi pé wön ngbin onírúurú tòmátì tí kò seé jç fún ayçyç ôlödôôdún yìí lásán. Ayçyç nbêrê ní déédé aago mëwàá òwúrõ nígbàtí àwôn akópa yóò máa sáré láti gbá çsê çlëdê tí wön so mö ara òpó kan tí nyõ mú. Àwôn olùwòran á máa tç omi sí wôn lára bí wön se nlàkàkà láti gun òpó yì í, tí wön si nkôrin, tí wön njó lójú pópó. Nígbàtí aago söõsì bá lu ti õsán, àwôn ôkõ akërù tí ó kún fún tòmátì á wõlú, bëê ni ariwo “Tò-má-tì, tò-má-tì” á gba gbogbo agbègbè kan. Lëyìn èyí pêlú yínyin ìbôn olómi, ojúlówó ayçyç bêrê ní pçrçwu. Èyí ni ìbêrê fífö àti jíju tòmátì mô ara çni. Àwôn tí ó jë pé láti òkèèrè ni wön ti nju tòmátì ti wôn, àwôn tí wön ní çni tí wön fi ti wôn sùn, àti àwôn tí wôn kò jìnnà púpõ sí ojú agbo, gbogbo wôn náà ni wön sáà nju tòmátì bí wön se fë. Èyíkéyìí õnà tí o leè gbà máa jù ú, nígbàtí yóò bá fi di òpin ohun gbogbo, wàá wo ara rç (ó sì mö lára) pé o ti yàtõ. Lëyìn nkan bí wákàtí kan ó dín díê, ó ku kí àwôn tí omi tòmátì ti mù dùndùndùn máa seré nínú agbami tòmátì tí ó ti rõ dòmù-dòmù tí ó kún lê, tí ò tiê sì jô tòmátì mö. Yínyín ìbôn lëêkejì ni ó nse àmìn òpin ìjàgbùdù náà. | Entry #21047 — Discuss 0 — Variant: Not specifiednone
Voting points | 1st | 2nd | 3rd |
---|
0 | 0 | 0 | 0 |
- 1 user entered 1 "dislike" tag
- 1 user agreed with "dislikes" (1 total agree)
+1 1 Taani çni tí ó ju tòmátì àkökö èyí tí ó bêrê àsà tòmátì jíjù mö ara çni? Òtítö ibê ni wí pe kò sí çni tí ó leè sô | Spelling There is a problem with the tonal marks used. | Abiodun Adeleye | |
| | | | | X Sign in to your ProZ.com account... | | | | | | ProZ.com translation contestsProZ.com translation contests offer a fun way to take a break from your normal routine while testing and honing your skills with fellow translators.
ProZ.com Translation Contests. Patent pending. |